Baba Pami Lerin Ayo (My Aspiration) by Yinka Ayefele Mp3 Download
Yinka Ayefele just dropped a vibe titled Baba Pami Lerin Ayo (My Aspiration). Yinka Ayefele is a Nigerian gospel musician, singer, producer, and media entrepreneur.he transformed his life through music, becoming one of Nigeria’s most celebrated and resilient gospel artists. Enjoy the magic in every note.
Simply use the link below to stream and download Baba Pami Lerin Ayo (My Aspiration) by Yinka Ayefele.
Lyrics of Baba Pami Lerin Ayo (My Aspiration) by Yinka Ayefele
Baba pá mí l’ẹrin ayo, kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba AtoriseBaba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin é logoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba Atorise
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Airi na àìrí o aiye, baba mi kuro l’ọnaỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miAiri na airi ibi aiye baba mu kuro l’ọnaỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miKeṣu wa ribi ko subu ni waju mi oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJeki satani ko subu ni waju mi oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jẹ kí ọrọ mí dijo, jẹ kí ọrọ mí na sayoỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJẹ kí ọrọ mí dijo, kí ọrọ mí ja sayoỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miOhun t’aye ro pe ko ṣẹṣẹ ọlọrun wá bá mi ṣe o
Baba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba AtoriseBaba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba Atorise
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJeki gbogbo ibi èsù já, mu ibi kuro l’ọna miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJeki gbogbo ibi èsù já mu ibi kuro l’ọna miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miNipa agbara ẹjẹ Jesu ọlọrun wa ṣe ògoỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miNípa agbára eje Jesu ọlọrun wa ṣe ògo oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Nípa agbára eje Jesu ọlọrun wa ṣe ògo oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJẹ kí ọrọ mí dijo ijo oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJẹki ọrọ mí dijo, ijo ayo ni t’emiỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJeki oro mi dijo, fi oyin fadun sí ọrọ míỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miṢọrẹ ti ayé a ri pe ọlọrun ló ṣogò ayé mi oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miṢọrẹ ti ayé a ri pe ọlọrun ló ṣogò ayé mi o
Baba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba AtoriseBaba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba Atorise
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Airi na àìrí o aiye, baba mi kuro l’ọnaỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miAiri na airi ibi aiye baba mu kuro l’ọnaỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miKeṣu wa ribi ko subu ni waju mi oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJeki satani ko subu ni waju mi oỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miJẹ kí ọrọ mí dijo, kí ọrọ mí ja sayoỌlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su miOhun t’aye ro pe ko ṣẹṣẹ ọlọrun wá bá mi ṣe o
Baba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba AtoriseBaba pá mí l’ẹrin ayo kín le yin ọ l’ogoOhun t’aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenuỌba onile Ayo, ọba Atorise
Up Jesus, down Satan
Leave a Reply